Jẹ́nẹ́sísì 29:30 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jákọ́bù sì bá Rákélì náà lòpọ̀. Ó sì fẹ́ràn Rákélì ju Líà lọ, ó sì ṣiṣẹ́ sin Lábánì fún ọdún méje mìíràn.

Jẹ́nẹ́sísì 29

Jẹ́nẹ́sísì 29:20-32