Jẹ́nẹ́sísì 29:28 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jákọ́bù sì gbà láti sin Lábánì fún ọdún méje mìíràn. Lábánì sì fi Rákélì ọmọ rẹ̀ fún un bí aya.

Jẹ́nẹ́sísì 29

Jẹ́nẹ́sísì 29:19-35