Jẹ́nẹ́sísì 29:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jákọ́bù sì fẹnu ko Rákélì ní ẹnu. Ó sì bẹ̀rẹ̀ sí í sọkún.

Jẹ́nẹ́sísì 29

Jẹ́nẹ́sísì 29:6-18