Jẹ́nẹ́sísì 28:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kí Ọlọ́run Olódùmarè kí ó bùkún fún ọ, kí ó sì mú ọ bí sí i, kí ó sì mú ọ pọ̀ sí i ní iye títí tí ìwọ yóò di àgbájọ àwọn ènìyàn.

Jẹ́nẹ́sísì 28

Jẹ́nẹ́sísì 28:1-10