Jẹ́nẹ́sísì 28:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sì lá àlá pé, a gbé àkàsọ̀ kan dúró ti ó fi ìdí lélẹ̀, orí rẹ̀ sì kan ọ̀run, àwọn ańgẹ́lì Ọlọ́run sì ń gòkè, wọ́n sì ń sọ̀kalẹ̀ lórí rẹ̀.

Jẹ́nẹ́sísì 28

Jẹ́nẹ́sísì 28:2-17