Jẹ́nẹ́sísì 27:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Rèbékà sọ fún Jákọ́bù ọmọ rẹ̀ pé, “Wò ó, mo gbọ́ tí baba rẹ ń bá ẹ̀gbọ́n rẹ sọ̀rọ̀ pé,

Jẹ́nẹ́sísì 27

Jẹ́nẹ́sísì 27:1-9