Jẹ́nẹ́sísì 27:43 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí náà ọmọ mi, ṣe ohun tí èmi yóò sọ fún ọ: Ṣá lọ sọ́dọ̀ Lábánì ẹ̀gbọ́n mi ní Háránì.

Jẹ́nẹ́sísì 27

Jẹ́nẹ́sísì 27:34-46