Jẹ́nẹ́sísì 27:41 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ísọ̀ sì kóríra Jákọ́bù nítorí ìre tí baba rẹ̀ sú fún un, ó sì wí fún ara rẹ̀ pé, “Baba mi ṣáà ti fẹ́rẹ̀ẹ́ kú, nígbà náà ni èmi ó pa Jákọ́bù, arákùnrin mi.”

Jẹ́nẹ́sísì 27

Jẹ́nẹ́sísì 27:32-46