Jẹ́nẹ́sísì 27:36 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ísọ̀ sì wí pé, “Lásán ni a pe orúkọ rẹ̀ ní Jákọ́bù, (Arẹ́nijẹ) bí? Ní ìgbà méjì yìí ni ó ti tàn mí jẹ: ní àkọ́kọ́, ó gba ogún ìbí mi, nísinsinyìí, ó tún gba ìbùkún mi! Áà! Baba mi, ṣe o kò wá fi ìre kankan sílẹ̀ fun mi ni?”

Jẹ́nẹ́sísì 27

Jẹ́nẹ́sísì 27:29-44