Jẹ́nẹ́sísì 27:32 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìsáákì baba rẹ̀ sì bi í wí pé, “Ìwọ ta ni?” Ó sì dáhùn pé “Èmi Ísọ̀, àkọ́bí rẹ ni.”

Jẹ́nẹ́sísì 27

Jẹ́nẹ́sísì 27:22-35