Jẹ́nẹ́sísì 27:30 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí Ísáákì ti súre tan tí Jákọ́bù ṣẹ̀ṣẹ̀ jáde kúrò ní ọ̀dọ̀ baba rẹ̀ ni Ísọ̀ ti oko ọdẹ dé.

Jẹ́nẹ́sísì 27

Jẹ́nẹ́sísì 27:27-35