Jẹ́nẹ́sísì 27:26 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà náà ni Ísáákì baba rẹ̀ wí fun un pé, “Súnmọ mi, ọmọ mi, kí o sì fẹnu kò mí ní ẹnu.”

Jẹ́nẹ́sísì 27

Jẹ́nẹ́sísì 27:21-35