Jẹ́nẹ́sísì 27:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìwọ yóò sì gbé e tọ baba rẹ lọ, kí òun baà lè jẹ ẹ́, kí ó sì súre fún ọ kí ó tó kú.”

Jẹ́nẹ́sísì 27

Jẹ́nẹ́sísì 27:1-17