Jẹ́nẹ́sísì 26:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

nítorí pé Ábúráhámù gbọ́ràn sí mi lẹ́nu, ó sì pa gbogbo ìkìlọ̀, àṣẹ, ìlànà àti òfin mi mọ́.”

Jẹ́nẹ́sísì 26

Jẹ́nẹ́sísì 26:1-10