Jẹ́nẹ́sísì 26:29 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

pé ìwọ kì yóò ṣe wá ní ibi, bí àwa pẹ̀lú kò ti ṣe ọ́ ní aburú, tí a sì ń ṣe ọ́ dáradára, tí a sì rán ọ jáde ní àlàáfíà láì ṣe ọ́ ní ibi, kíyèsi Olúwa sì ti bùkún fún ọ.”

Jẹ́nẹ́sísì 26

Jẹ́nẹ́sísì 26:27-35