Jẹ́nẹ́sísì 26:27 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ísáákì sì bi wọ́n léèrè pé, “Èéṣe tí ẹ̀yin tọ̀ mí wá, níwọ̀n ìgbà tí ẹ̀yin kórìra mi tí ẹ sì lé mi jáde kúrò lọ́dọ̀ yin?”

Jẹ́nẹ́sísì 26

Jẹ́nẹ́sísì 26:24-35