Jẹ́nẹ́sísì 26:22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sì tún kúrò níbẹ̀, ó sì gbẹ́ kànga mìíràn, wọn kò sì já sí èyí rárá, ó sì pe orúkọ rẹ̀ ní Réhóbótì, ó wí pé, “Nísinsìnyìí, Olúwa ti fi àyè gbà wá, a ó sí i gbilẹ̀ sì ni ilẹ̀ náà.”

Jẹ́nẹ́sísì 26

Jẹ́nẹ́sísì 26:20-25