Jẹ́nẹ́sísì 26:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn ìránṣẹ́ Ísáákì sì gbẹ́ kànga ní àfonífojì náà, wọ́n kan ìsun omi níbẹ̀.

Jẹ́nẹ́sísì 26

Jẹ́nẹ́sísì 26:11-28