Jẹ́nẹ́sísì 25:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ábúráhámù sì kú ní ọjọ́ ogbó rẹ̀. Ó dàgbà, ó darúgbó kí ó tó kú. A sì sin in sí ibojì àwọn ènìyàn rẹ̀.

Jẹ́nẹ́sísì 25

Jẹ́nẹ́sísì 25:1-10