Jẹ́nẹ́sísì 25:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn ọmọ Mídíánì ni Éfánì, Éférì, Ánókù, Ábídà àti Élídà. Gbogbo àwọn wọ̀nyí ni ìran Kétúrà.

Jẹ́nẹ́sísì 25

Jẹ́nẹ́sísì 25:1-10