Jẹ́nẹ́sísì 25:28 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ísáákì, ẹni tí ó fẹ́ràn ẹran-ìgbẹ́ fẹ́ràn Ísọ̀ nítorí ẹran ìgbẹ́ tí Éṣáù máa ń pa, ṣùgbọ́n Rèbékà fẹ́ràn Jákọ́bù.

Jẹ́nẹ́sísì 25

Jẹ́nẹ́sísì 25:21-34