Jẹ́nẹ́sísì 25:26 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Lẹ́yìn rẹ̀ ni èyí èkejì jáde, ó sì di arákùnrin rẹ̀ ni gìgíṣẹ̀ mú, nítorí náà ni wọn ṣe pe orúkọ rẹ ni Jákọ́bù. Ọmọ ọgọ́ta ọdún ni Ísáákì, nígbà tí Rèbékà bí ìbejì yìí fún un.

Jẹ́nẹ́sísì 25

Jẹ́nẹ́sísì 25:16-34