Jẹ́nẹ́sísì 25:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ísáákì sì gbàdúrà sì Olúwa, nítorí aya rẹ̀ tí ó yàgàn, Olúwa sì gbọ́ àdúrà rẹ̀, Rèbékà sì lóyún.

Jẹ́nẹ́sísì 25

Jẹ́nẹ́sísì 25:12-22