Jẹ́nẹ́sísì 25:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọ̀nyí ni ìran Íṣímáélì, ọmọ Ábúráhámù ẹni tí Hágárì ará Éjíbítì, ọmọ ọ̀dọ̀ Ṣárà bí fún un.

Jẹ́nẹ́sísì 25

Jẹ́nẹ́sísì 25:7-17