Jẹ́nẹ́sísì 25:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Inú oko tí Ábúráhámù rà lọ́wọ́ ara Hítì yìí ni a sin Ábúráhámù àti Ṣárà aya rẹ̀ sí.

Jẹ́nẹ́sísì 25

Jẹ́nẹ́sísì 25:9-20