Jẹ́nẹ́sísì 24:43 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wò ó, mo dúró ní ẹ̀gbẹ́ ìsun omi yìí, kí ó ṣe pé, nígbà tí wúndíá kan bá jáde wá pọn omi, tí èmi sì wí fún un pé, “Jọ̀wọ́ fún mi ní ìwọ̀nba omi díẹ̀ mu nínú ládugbó rẹ”,

Jẹ́nẹ́sísì 24

Jẹ́nẹ́sísì 24:38-51