Jẹ́nẹ́sísì 24:37 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Olúwa mi sì ti mú mi búra wí pé, ‘Ìwọ kò gbọdọ̀ fẹ́ aya fún ọmọ mi, láàrin àwọn ọmọbìnrin Kénánì, ní ilẹ̀ ibi tí èmi ń gbé,

Jẹ́nẹ́sísì 24

Jẹ́nẹ́sísì 24:32-44