Jẹ́nẹ́sísì 24:30 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí ó sì ti rí òrùka imú àti ẹ̀gbà ní ọwọ́ arábìnrin rẹ̀ tí ó sì tún gbọ́ ohun tí Rèbékà sọ pé ọkùnrin náà sọ fún òun, ó jáde lọ bá ọkùnrin náà, ó sì bá a, ó dúró ti ràkunmí wọ̀n-ọn-nì ní ẹ̀bá ìsun-omi.

Jẹ́nẹ́sísì 24

Jẹ́nẹ́sísì 24:22-40