Jẹ́nẹ́sísì 24:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Láì sọ ọ̀rọ̀ kan, ìránṣẹ́ yìí ń wo ọmọbìnrin náà fínnífínní láti mọ̀ bóyá Ọlọ́run ti ṣe ìrìn-àjò òun ní rere tàbí bẹ́ẹ̀ kọ́.

Jẹ́nẹ́sísì 24

Jẹ́nẹ́sísì 24:17-25