Jẹ́nẹ́sísì 24:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kí o tó di pé, ó parí àdúrà, Rèbékà dé pẹ̀lú ìkòkò omi rẹ̀ ní èjìká rẹ̀. Ọmọ Bétúélì ni. Bétúélì yìí ni Mílíkà bí fún Náhórì arákùnrin Ábúráhámù.

Jẹ́nẹ́sísì 24

Jẹ́nẹ́sísì 24:5-19