Jẹ́nẹ́sísì 23:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Olúwa mi, gbọ́ tiwa, ó jẹ́ alágbára ọmọ-aládé láàrin wa, sin òkú rẹ sí ibojì tí ó dárajù nínú àwọn ibojì wa, kò sí ẹni tí yóò fi ibojì rẹ dùn ọ́ láti sin òkú rẹ sí.”

Jẹ́nẹ́sísì 23

Jẹ́nẹ́sísì 23:1-11