Jẹ́nẹ́sísì 23:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ábúráhámù sì dìde lẹ́gbẹ̀ẹ́ òkú aya rẹ̀, ó sì sọ fún àwọn ará Hítì wí pé,

Jẹ́nẹ́sísì 23

Jẹ́nẹ́sísì 23:1-13