Jẹ́nẹ́sísì 23:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Lẹ́yìn náà ni Ábúráhámù sin aya rẹ̀ Sárà sínú ihò àpáta ní ilẹ̀ Mákípélà nítòòsí Mámúrè (tí í ṣe Ébúrónì) ní ilẹ̀ Kénánì.

Jẹ́nẹ́sísì 23

Jẹ́nẹ́sísì 23:12-20