Jẹ́nẹ́sísì 22:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

dájúdájú, Èmi yóò bùkún ọ, Èmi yóò sì mú kí ìran rẹ yìí kí ó pọ̀ bí i ìràwọ̀ ojú ọ̀run àti bí i yanrìn etí òkun. Irú ọmọ rẹ yóò sì gba ẹnu ibodè àwọn ọ̀ta wọn,

Jẹ́nẹ́sísì 22

Jẹ́nẹ́sísì 22:7-24