Jẹ́nẹ́sísì 22:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà tí ó ṣe, Ọlọ́run dán Ábúráhámù wò, ó pè é, ó sì wí pé, “Ábúráhámù.”Ábúráhámù sì dáhùn pé, “Èmi nìyí.”

Jẹ́nẹ́sísì 22

Jẹ́nẹ́sísì 22:1-4