Jẹ́nẹ́sísì 21:27 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ábúráhámù sì mú àgùntàn àti màlúù wá, ó sì kó wọn fún Ábímélékì. Àwọn méjèèjì sì dá májẹ̀mú.

Jẹ́nẹ́sísì 21

Jẹ́nẹ́sísì 21:24-29