Jẹ́nẹ́sísì 21:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ábúráhámù sì dìde ní kùtùkùtù òwúrọ̀ ọjọ́ kejì, ó sì mú oúnjẹ àti ìgò omi kan, ó sì kó wọn fún Ágárì, ó kó wọn lé e léjìká, ó sì lé e jáde pẹ̀lú ọmọ náà. Ó sì lọ lọ́nà rẹ, ó sì ń ṣe alárìnkiri ní ijù Báá-Ṣébà.

Jẹ́nẹ́sísì 21

Jẹ́nẹ́sísì 21:13-15