Jẹ́nẹ́sísì 20:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Níṣinyìí, dá aya ọkùnrin náà padà, nítorí pé wòlíì ni, yóò sì gbàdúrà fún ọ, ìwọ yóò sì yè. Ṣùgbọ́n bí ìwọ kò bá dá a padà, mọ̀ dájú pé ìwọ àti gbogbo ẹni tíí ṣe tìrẹ yóò kú.”

Jẹ́nẹ́sísì 20

Jẹ́nẹ́sísì 20:2-12