Jẹ́nẹ́sísì 20:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ábímélékì sì tún wí fún un pé, “Gbogbo ilé mí nìyí níwájú rẹ, máa gbé ní ibikíbi tí o fẹ́ níbẹ̀.”

Jẹ́nẹ́sísì 20

Jẹ́nẹ́sísì 20:7-16