Jẹ́nẹ́sísì 20:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Yàtọ̀ fún ìyẹn, òtítọ́ ni pé arábìnrin mi ni. Ọmọ baba kan ni wá, bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé, a kì í ṣe ọmọ ìyá kan. Mo sì fẹ́ ẹ ní aya.

Jẹ́nẹ́sísì 20

Jẹ́nẹ́sísì 20:11-16