Jẹ́nẹ́sísì 2:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Olúwa Ọlọ́run sì mọ ènìyàn láti ara erùpẹ̀ ilẹ̀, ó si mí èémí sí ihò imú rẹ̀, èémí ìyè, ènìyàn sì di ẹ̀dá alààyè.

Jẹ́nẹ́sísì 2

Jẹ́nẹ́sísì 2:1-12