Jẹ́nẹ́sísì 2:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èyí ni ìtàn bí Ọlọ́run ṣe dá àwọn ọ̀run àti ayé nígbà tí ó dá wọn.Nígbà tí Olúwa Ọlọ́run dá ayé àti àwọn ọ̀run,

Jẹ́nẹ́sísì 2

Jẹ́nẹ́sísì 2:1-6