Jẹ́nẹ́sísì 2:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Olúwa Ọlọ́run wí pé, “Kò dára kí ọkùnrin wà ní òun nìkan. Èmi yóò ṣe olùrànlọ́wọ́ tí ó rí bí i rẹ̀ fún un.”

Jẹ́nẹ́sísì 2

Jẹ́nẹ́sísì 2:17-21