Jẹ́nẹ́sísì 2:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Orúkọ odò kẹta ni Tígírísì: òun ni ó sàn ní apá ìlà oòrùn ilẹ̀ Áṣúrì. Odò kẹ́rin ni Yúfúrátè.

Jẹ́nẹ́sísì 2

Jẹ́nẹ́sísì 2:13-21