Jẹ́nẹ́sísì 19:30 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Lọ́tì àti àwọn ọmọ rẹ̀ obìnrin méjèèjì sì kúrò ní Sóárì, wọ́n sì ń lọ gbé ní orí òkè ní inú ihò-àpáta, nítorí ó bẹ̀rù láti gbé ní ìlú Sóárì.

Jẹ́nẹ́sísì 19

Jẹ́nẹ́sísì 19:24-36