Jẹ́nẹ́sísì 19:27 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní kùtùkùtù òwúrọ̀ ọjọ́ kejì, Ábúráhámù sì dìde ó sì padà lọ sí ibi tí ó gbé dúró níwájú Olúwa.

Jẹ́nẹ́sísì 19

Jẹ́nẹ́sísì 19:20-28