Jẹ́nẹ́sísì 18:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sì tún sáré lọ sí ibi agbo ẹran, ó sì mú ọmọ màlúù kan fún ìránṣẹ́ rẹ̀, ìránṣẹ́ náà sì tètè ṣè é.

Jẹ́nẹ́sísì 18

Jẹ́nẹ́sísì 18:1-9