Jẹ́nẹ́sísì 18:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹ jẹ́ kí a bu omi díẹ̀ wá kí ẹ̀yin kí ó wẹ ẹṣẹ̀ yín, kí ẹ sì sinmi lábẹ́ igi níhìn-ín.

Jẹ́nẹ́sísì 18

Jẹ́nẹ́sísì 18:1-7