Jẹ́nẹ́sísì 18:29 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Òun sì tún wí lẹ́ẹ̀kan si pé, “Bí ó bá ṣe pé ogójì (40) ni ńkọ́?” Olúwa sì tún wí pé, “Èmi kì yóò pa ìlú náà run bí mo bá rí olódodo ogójì nínú rẹ̀.”

Jẹ́nẹ́sísì 18

Jẹ́nẹ́sísì 18:27-33