Jẹ́nẹ́sísì 18:26 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Olúwa wí pé, “Bí mo bá rí àádọ́ta (150) olódodo ní ìlú Ṣódómù, èmi yóò dá ìlú náà sí nítorí tí wọn.”

Jẹ́nẹ́sísì 18

Jẹ́nẹ́sísì 18:20-33